Smiley face
Showing posts with label Iroyin Agbaye. Show all posts
Showing posts with label Iroyin Agbaye. Show all posts

Ajalu sele niluu London: eniyan marun un ku, ogoji farapa

Awon eniyan ti won fura si gege bi alakatakiti agbesunmomi gbiyanju lati kolu ile igbimo ile Biritiko lana, 22:03:07. 
Read More

Awon oyinba pon Oonirinsa le niluu London: Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi gbayi niluu Oba

Ka ma paro, awon oyinbo se aponle Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi niluu London. Won se alaye Arole Oodua gege bi ologbon eda ati asaaju to s...
Read More

Orekelewa obabirin MOREMI gbe asa Yoruba soke niluu London

  Sebi e mo wi pe Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi si wa niluu London, lara awon to koworin pelu Ojaja II ni Obabirin Moremi asiko yii eley...
Read More