Smiley face

'Ogun Ni Lola Alao Fe Fi Ba Aye Mi Je' Oko Lola

Leyin igbeyawo alarinrin to waye laaarin Lola Alao ati Dare to je onisowo moto eleyii to pada tuka bi feere ti won fon lafonju, oko re ti pada tu asiri oro wi pe ogun ni Lola Alao n lo fun oun.

"Bi mo se se igbeyawo pelu re gan-an ko ye mi rara. Oro naa dabi ala loju mi ni. Moto meji ni mo ra fun un, ti mo si gba ile nla kan fun oun ati awon ebi re. Osoosu ni mo fun ni egberun lona ogorin naira ko maa ri ohun fi sapo.

Gbogbo ibadi Lola, asan gbere lo kun ibi. Gbogbo igba lo maa n mu mi lo sile oloogun tori ki ise mi le tesiwaju, a se iro ni gbogbo e. Ona la ti je mi run ni Lola n san. A mo mo dupe, Edumare ti ko mi yo" Dare
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment