Olori egbe adigunjale ti oruko re n je Hussein Shaban ti o ti fi igba pipe da awon eniyan apa oke oya loro laimoye igba ni owo ti te bayii.
Awon eniyan ko tile reti idajo lati odo ijoba ki won to se okunrin naa bi won se fe nikete ti owo te e.
Ojo gbogbo ni tole, ojo kan ni ti 'the owner'
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment