Smiley face

Igba Otun Ti De Ba Banki Naijeria

Sebi won ni bi ojumo se n mo ni imo ijinle n peleke sii.

Lara igba otun to de ba Banki ile wa ni ona ti onibara fi le fowo pamo sinu apo ifowopamo banki re nipa lilo eyikeyi banki to ba wa ni arowoto re.

Eyi ni wi pe onibara le ni apo ifowopamo pelu EcoBank ko si fi owo pamo sinu apo ifowopamo re nipa lilo Wema Bank tabi eyikeyi banki to wa ni itosi re.

Ko pondandan fun onibara banki kan ko de banki re gan-angan ko to le fowo pamo.

Bi o se je wi pe ko si ATM banki ti onibara ko le lo, bakan naa lo je wi pe ko si banki ti onibara ko le lo lati fi owo pamo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment