Smiley face

[Foto] Aare Goodluck Jonathan Laafin Awon Oba Alaye

Aare Goodluck se abewo si aafin awon oba alaye lati pe fun ipade apapo orile Naijeria sugbon opolopo awon eniyan gba wi pe abewo naa mu ifura dani eleyii to seese ko je lara ete Aare lati pada wole gege bi Aare ninu eto idibo odun ti n bo.[ E ka afikun iroyin nibi]

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment