
Aarẹ ilẹ Naijẹria nigba kan ri, Olusegun Obasanjo wa ni ilu Port Harcourt lana ọjọ Aje (February 17,2014) lati se ifilọlẹ awon ise akanse ti Gomina Rotimi. A gbọ wi pe gomina lo fi iwe pe Baba Iyabọ lati wa se ifilọlẹ naa. Nibi ti Ẹbọra ti ilu Owu ti n se ifilọlẹ lo ti foju kan ogẹdẹ àgbagbà lo ba fa àdá yọ lo si ge lulẹ. Baba sọ wi pe ogẹdẹ naa yoo wulo ti oun ba pada silẹ.


0 comments:
Post a Comment