Smiley face

Awon Olopa Ti Mu Baba Olowo Ti N Ba Omo Ile Iwe Sun Ninu Igbo

Ipinle Benue ni isele yii ti sele, okunrin olowo kan ni enikan ka mo ibi to ti n ba omo ile iwe, omo kekere sun ni inu igbo. Eni yii lo ke si awon olopa lori ago. Igba ti Olorun Oba Eleburuuke yoo mu baba yii lorun owo, won ka jagunlabi mo ibi to ti n kona fun omo naa lowo ni olopa alaso dudu ba jan ni kondo lori.

Oruko okunrin yii ko ti jade si wa lowo. Sugbon a gbo wi pe eniyan nla ni, won si n gbiyanju lati fi oruko bo lasiri.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment