Smiley face

Davido Ati Baba Olowo



Baba to bi Davido, Alagba Deji Adeleke pe eni odun metadinlogota (57) lana, awon omo re si rogba yika lati ba a fi ope fun Oluwa Oba.

Igba odun, odun kan ni!


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment