Ashkan Dejagah omo ilu Iran to tun je omo egbe agbaboolu Fulham lo ti leri lati fi iya nla je Super Eagle ninu ifesewonse akoko ti yoo waye laaarin Iran ati Nigeria ninu idije boolu agbaye, Brazil World Cup 2014.
Ile Naijeria yoo maa bere idije boolu agbaye ti yoo waye ni Brazil pelu ifesewonse won akoko ti yoo waye ni ojo kerindinlogun osu kefa odun yii pelu iko egbe agbaboolu ilu Iran ni ilu Curitiba.
Isori F ni Nigeria wa pelu Iran,Bosnia-
Herzegovina ati Argentina.
Awon Yoruba so wi pe eniyan kii jiyan bi ose ho bi ko ho lodo. Ipade di ojo na naa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment