![]() |
| Otunba Olasubomi ati aya re, Olori Abimbola Adetutu |
Oludasile ati alagba ile ise ifowopamo FCMB. Otunba Michael Olasubomi Balogun se ayeye ojo ibi ogorin odun (80) lopin ose to koja yii ni ilu Eko. Lara awon eniyan to wa sibe ayeye naa ni HRH Oba Akiolu ti ilu Eko, Arabirin Abimbola aya gomina Fashola, Dele Momodu, Gomina Ibikunle Amosun, ajinhinrere Ebenezer Obe ati opolopo awon eniyan jankanjanjan lawujo ni won peju pese sibi ayeye naa.



Akara Oyinbo
Akara oyinbo









0 comments:
Post a Comment