Iwe iroyin The Sun tile wa ti gbe jade wi pe Ogbeni Rauf Aregbesola ti o je gomina Ipinle Osun ti lo se ipade idakonko pelu gomina ipinle naa nigba kan ri, Olagunsoye Oyinlola ni ojo Aje to koja yii ni ile re to wa ni Okuku ni Ijoba Ibile Odo-Otin.
Ko si enikeni to le so pato ohun ti gomina Rauf Aregbesola lo ri Oyinlo fun. Lara awon ti a tun gbo wi pe won se ipade po pelu Baba Kofo ni ojo kan naa yii ni Ojogbon Olusola Adeyeye ti n soju Osun Central Senatorial District ni ile Igbimo Asofin Agba l'Abuja.
http://sunnewsonline.com/new/?p=60794

0 comments:
Post a Comment