Aare ile Amerika, Barack Obama ti fi aidunnu re han nipa ijamba buruku to sele ni ilu Abuja eleyii ti apapo awon eniyan ti won ba isele naa lo je mokanlelaadorin (71) nigba ti awon eniyan ti won selese n lo bi ogofa (120).
Aare Obama lo n gba enu Jen
Psaki to je asoju ile ijoba soro pelu gbolohun yii:
"We are outraged by this senseless act of violence against innocent civilians,"
Gege bi a se gbo, won ni o seese ki won tun fi kun iye awon eniyan ti won ku nigba ti won si n gbiyanju lati se ayewo ajaku oku awon eniyan ti won ku nibi isele naa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment