Smiley face

Ogun Aye Bori Wasley Ni Ilu Amerika

Ogun ni ile aye, eni ba ja ajaye lo segun. Wasley Warren Jr to n gbe ni Las Vegas ni ilu America ko se aisan tele ko to kan agbako eru banban ti aye so mo o nidi. O ji lojo kan naa lo sadeede ri wi pe epon re n wu, ara bere si ni nii, ko si gbadun ara re gege bi eda eniyan mo lati igba naa wa. Opolopo awon eniyan ti won ba ri, erin ni won fi n rin latari kondisan re to kiritika.
 
 
"There are a lot of people that will look and laugh and stare in shock and awe and amazement and it's tough to deal with."


Wasley ko lowo dani lati se ise abe sugbon ko fi oro re bo lori Facebook nibi ti awon kan ti dide lati se iranlowo owo fun ise abe re.
 
Won sise abe fun un, eleyii to gba awon dokita ilu Amerika ni odindin wakati metala (13) ki won to yanju isoro aye re.
 
"I cannot express how ecstatic I'm feeling about the future," oro yii lo jade lenu re leyin ti won sise abe fun un tan.
 
"And if some way somehow or another I can stumble upon love – any kind of love – I think I will finally be happy.
 
"I'm very thankful that I've been given my life back."
 
 
Ninu osu keta odun yii, leyin odun kan ti Wasley ti n gbe aye alaafia, okan re tun dake ise (heart attack) eleyii to mu emi re lo ni eni odun mokandinlaadota (49).
 
 
Olayemi Oniroyin mo gbadura, ogun aye ko ni bori enikeni ninu wa o. Amin.
 
E ku ikale!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment