Oga Nla ti ilu Amerika, Diddy eleyii ti iwe iroyin Magasiini Forbes gbe jade gege bi olorin takasufe to lowo ju lagbaye ti se afihan awon omo re mefa nibi ajoyo odun ajinde to koja yii. Awon omo mefa yii lagbo wi pe orisii obirin meta naa lo bi awon omo naa fun un.
Edumare ba wo omo fun olomo.Baba mimo, ba wa pese omo rere fun awon ti n woju re. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment