Smiley face

[Foto] Isan Banky W Ti Di Iroyin Fun Gbogbo Aye

Omo okunrin olorin, Banky W ti pada si yara akanse ere idaraya eleyii ti yoo mu gbogbo isan ara re dide gege bi alagbara kaka. Omokunrinn ti abiso re n je Olubankole ti a bi lodun 1981 ti se afihan aworan ara re tuntun lati je ka mo  ibi ti akitiyan re de duro nipa ara re. 

" allOfUsMustOffShirt #GatsBeSexyByFireByForce "

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment