Smiley face

Olukoni Egbe Agba Boolu Brazil Ti Binu Fi Ipo Re Sile

Olukoni egbe agba boolu Brazil, Luiz Felipe Scolari ti kowe fi ipo re sile gege bi olukoni egbe naa leyin ti ilu Brazil kuna lati gba ifi eye agbaye odun 2014 to wa sopin lai pe yii.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment