Arun buruku kogboogun ebola ti paayan kan bayii ni ilu Eko nigba ti won tun fura si awon mejo mii wi pe oseese ki won ti fara kasa arun buruku naa. Konisanna fun eto ilera Ipinle Eko, Dokita Jide Idris lo ja wa si.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)

0 comments:
Post a Comment