Oni ogunjo osu kokanla lo je igba akoko ti awon omo ile igbimo asoju-sofin ile Nigeria yoo ma pada joko leyin igba ti olori won, Hon. Aminu Tambuawal ti ko eru re wonu egbe APC lati inu PDP.
Nnkan ko fararo rara pelu ogunlogo awon olopa alaso dudu se duro lenu ona to wole sinu ile igbimo asofin lati ri daju wi pe Tambuawal ko rona wole.
Awon kan ni ara ise owo Janathan ni, awon kan ni ofin ile Nigeria ni ile ise olopa n tele.
Ju gbogbo re lo, oro pada di fopomoyo nigba ti awon ololufe Tambuwal lati inu egbe onigbale so wi pe dandan ni ni ki Aminu wole sinu ile igbimo asofin lati se ojuse re.
E ma gbagbe wi pe ilu London ni Aare Jonathan wa nibi o ti gbe n yo ayo ojo ibi re lowo.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment