Smiley face

Alao Akala Fi Gbogbo Ara Jo Lojo Odun Keresimesi

Oludije fun ipo gomina Ipinle Oyo labe egbe oselu Labour Party, Christopher Adebayo Alao-Akala omo Iya Alaro jo yika ile ijo First Baptist Church to wa ni Ogbomoso lojo odun Keresimesi lati fi ope fun Oluwa.

Lara igbagbo Akala ni wi pe oun ni ipo gomina Ipinle Oyo tosi lodun 2015.

Lara awon oludije ti won yoo jo maa na tan bi owo ninu eto idibo naa ni Abiola Ajimobi (APC), Teslim Folarin (PDP), Rasheed Adewolu Ladoja (Accord), ati Seyi Makinde (SDP).
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment