Won Ti Ju Aburada Lu PDP Laya: Etteh Ni Ohun Se Egbe Jonathan Mo.
Olori ile igbimo asoju-sofin nigba kan ri, Hon Patricia Olubunmi Etteh ti fi egbe PDP sile bo sinu egbe APC bayii. Eto igbaniwole yii ni Gomina Rauf Aregbesola se fun-nu ni ekun Irewole, Ayedaade ati Isokan to wa ni Ipinle Osun.
0 comments:
Post a Comment