Smiley face

Ewe ati Egbo Ile Yoruba 1: OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE

Bi eeyan ba we tan ti gbogbo ara ba n ja je; tabi ti ara ba n ja eniyan je ni gbogbo igba; tabi ki kokoro wa lara eni naa gege bi kuruna tabi eyikeyi kokoro ara.

Iwadii ijinle awon agbalagba Yoruba fi ye wa wi pe kokoro inu eje lo n faa awon nnkan wonyii.

Otito Oogun re ni eleyii:

A o wa egbo igi ti Yourba n pe ni Akogun, a o gun po ti yoo kunna daada. Leyin eyi ni a o da sinu igo tabi ike, a o da omi
osan wewe to po die sii.


Lilo Re: A o ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje.

Eni ti o ba ni arun ogbe inu (Ulcer) ko
gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo omi lasan.

Orisun: HealthFirst
Atunko/Atunse: @OlayemiOniroyin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

21 comments:

  1. Ejo ara maan Jami je lekankan Kini mole se ejo

    ReplyDelete
  2. Ejoo. Kini mo le looking fun ori yiyun ati nkan ti o ma un dabi elubo ni isale irun?

    ReplyDelete
  3. Ara ma n jamije bi iseju mewa leyin ti mobawe tan pelu kankan sugbon see ole fa ki orikerike Ara komaa ro Yan?

    ReplyDelete
  4. Ara mi ma se kulukulu kakiri kini mo le lo?

    ReplyDelete
  5. Gbogbo ara lo maa n yun mi to si maa n se eje ti mo ba yun un tan,ki ni mo le lo si.

    ReplyDelete
  6. Ejowo nkon ma nse kulukulu lago arami kini molelo si

    ReplyDelete
  7. Ejo Baba, kini o mafa ki ese ma ta enia lati orukun si atelese

    ReplyDelete
  8. Ẹ jọ̀wọ́ kini mo lè lo fún ojú ara yiyun

    ReplyDelete
  9. Kini o ma nfa Ori to ngba yii ti o si npariwo Ati Ara yiyun

    ReplyDelete
  10. Ejo kini molelo,si ara ihunhun,,,ti o ba hun,mi oma le panpan

    ReplyDelete
  11. Ejo se ewe akogun no oruko mi Tori awon eniyan ko mo

    ReplyDelete
  12. E jowo sir kini mo le lo si ara yiyun,ti yo si tun maa le

    ReplyDelete
  13. Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download Now

    >>>>> Download Full

    Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download LINK

    >>>>> Download Now

    Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download Full

    >>>>> Download LINK

    ReplyDelete
  14. Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download Now

    >>>>> Download Full

    Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download LINK

    >>>>> Download Now

    Ewe Ati Egbo Ile Yoruba 1: Oogun Fun Gbogbo Kokoro Inu Eje - Iroyin Yoruba >>>>> Download Full

    >>>>> Download LINK y1

    ReplyDelete
  15. Ekasan sir, e jo kini Eniyan le lo fun oyi ti o ma nmu ori fifo wa. Ori yen ma nfo mi ki oyi to wa.

    ReplyDelete
  16. Thants very much

    ReplyDelete
  17. Kini eniyan lelo tin nkan barinkiri ninu Ara

    ReplyDelete
  18. Ekasa sir ki ni mo le lo ti oyun yio fi duro

    ReplyDelete
  19. E jowo sir kini mo le lo fun segede eke omode

    ReplyDelete
  20. Ejo sir kini mole lo ti Ara ban Yun mi ati oju Ara ti mo ba we tan

    ReplyDelete