Smiley face

Ewe ati egbo: Bayii ni a se le se iwosan songun-sogun, awoka ara ati lakuregbe

Eyi ni lilo ewe ati egbo ile Yoruba lati fi se iwosan songun-sogun, awoka ara ati lakuregbe.

Eroja: Koro pear oyinbo nla meje, adin dudu.

Ipese: A ma sa koro pear naa sinu oorun ti yoo gbe daada. Leyin eyi ni a ma lo ti yoo kunna daada. Ti a ba se eyi tan, a da adin dudu si i.

Lilo: A ma la sibi kan leemeta lojumo. Eyi tunmo si wi pe, a ma la sibi kan laaro, sibi kan losan ati lale. Bakan naa ni a ma fi para lojoojumo.


Olayemi Oniroyin kii se onisegun, iwadii lasan ni mo se lọwọ awon agba. Edumare to jẹ oluwosan, yo mu gbogbo wa lara da.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments:

  1. Thank you so much uncle Yemi oniroyin Olorun yio ma funyinse

    ReplyDelete