Smiley face
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts

Wọn tí fi bàálù gbé òkú Senator Mustapha Bukar padà sile

Senator Mustapha Bukar tí parí isẹ rẹ nílùú Abuja. Wọn tí fi bàálù gbé padà sí ìlú rẹ, Katsina. Kí Ọlọ́run Allah bá dárí gbogbo aise dééde ...
Read More

Kositọma dáadáa ní Buhari - Aláké tilẹ Ẹ̀gbá

"Kositọma dáadáa ní Buhari . Mo fọwọ́ síi kò padà wa nígbà kejì láti wá parí àwọn iṣẹ́ takuntakun tó ti bẹ̀rẹ̀ - Aláké tilẹ Ẹ̀gbá Oba A...
Read More

Ìdìbò kú oṣù mewaa, asofin méjì kú láàárín ọsẹ meji

Lẹ́yìn bí ọsẹ kan tí ọmọ ilẹ̀ igbimo aṣojú sofin n kan kù, Senator míì tún kù ní àárọ̀ òní ni ilu Abuja. Senator Mustapha Bukar to wá láti i...
Read More

Orin òwe, orín ọtẹ, orín Sai Buhari tí gba gbogbo Bauchi báyìí

Ni ìpínlẹ̀ Bauchi wọn kó Buhari jẹ́ bí "abinci". Lọja Satide to kọjá yìí ni èrò bí èrò mecca tú jáde láti yọ ayọ̀ ọdún mẹta tí Sa...
Read More

Àwọn ọ̀dọ́ tú jáde nítorí Akinwunmi Ambode

Omi lẹgbẹ àwọn ọ̀dọ́ ni wó  tú jáde láti ṣe iwode gege bí àpẹẹrẹ atileyin wọn fún gómìnà Akinwunmi Ambode láti jẹ gómìnà fún ìgbà kejì. Iwod...
Read More