Smiley face

Àwọn ọ̀dọ́ tú jáde nítorí Akinwunmi Ambode

Omi lẹgbẹ àwọn ọ̀dọ́ ni wó  tú jáde láti ṣe iwode gege bí àpẹẹrẹ atileyin wọn fún gómìnà Akinwunmi Ambode láti jẹ gómìnà fún ìgbà kejì. Iwode to wáyé lọjọ Satide, 31/03/2018, ní won  ṣe láàárín Meryland sì Ojota ni ìpínlẹ̀ Eko.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment