Smiley face

"Ìyẹ́ ni wọn o má wo lẹ́yìn ẹyẹ, wọn ò lẹ́yẹ mu"- Dino Melaye ń fọ lẹ́yìn to bọ lọ́wọ́ kondo ọlọ́pàá laarọ yìí nílùú Abuja

"Ìyẹ́ ni wọn o má wo lẹ́yìn ẹyẹ, wọn ò lẹ́yẹ mu"- Dino Melaye ń fọ lẹ́yìn to bọ lọ́wọ́ kondo ọlọ́pàá laarọ yìí nílùú Abuja.

Àárọ̀ yìí ni Iroyin fò kiri wí pé àwọn ọlọ́pàá alasọ dúdú tí mú Dino ni papakọ ofurufu Abuja nígbà tí Senator tí ń soju ìwọ oòrùn Kogi fẹ́ fò lọ sí Morroco.

Ṣùgbọ́n nígbà tí Dino ọmọ ẹnìkan-ó-láyé bẹ̀rẹ̀ si ni kọrin Ajekun-ìyá ni awọn askari bá yá ara wọn ní brain, ni wọn ba tú sílẹ̀ wí pé kò má lọ.

Dino ọkùnrin mẹta! Bí ògùn lọ ń lò ni kò yẹ wá. Àwọn kan ni ayaj lásán ni. Wọn ní wón fẹ́ mú, wọn ò ri mú. Bí wọn ṣe ń mú ní wón ju silẹ.

Dino ọkọ Buhari 😂!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment