Smiley face

Arsene Wenger tí kéde ifehinti rẹ

Ẹ kíyèsí, àlàyé to bá ti ní nọ́mbà kìí rújú. Nǹkan bí ọdún méjìlélógún lo fi tukọ̀ ẹgbẹ́ agbaboolu Arsenal gẹ́gẹ́ bí akonimọọgba. Igba mẹta lo gba ifi ẹyẹ Premier League, nígbà tí ifi ẹyẹ FA jẹ ìgbà méje. Ní báyìí, Arsene Wenger tí kéde ifehinti rẹ tí sáà yìí bá parí. Ẹ wá bá wà wí fún wọn nílé Alárá, bi ẹ délé Ajero ẹ ṣàlàyé, ẹ sọ fún wí pé àwa mọ Arsene Wenger léèyàn pàtàkì. Ire

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment