Smiley face
Showing posts with label Ere Idaraya. Show all posts
Showing posts with label Ere Idaraya. Show all posts

Ọwọ Anthony Joshua, ọmọ ológo, ni àgbà wá báyìí

Ẹ wí fún ẹni tí kò bá mọ kí wọn lọ mọ wí pé, ọwọ́ Anthony Oluwafemi Olaseni Joshua nìkan ni ẹ ti lè rí àmì ẹyẹ agbaye WBA, IBF, WBO ati IBO....
Read More

Anthony Joshua Oluwafemi to bẹru

Anthony Olaseni Oluwafemi Joshua ṣe àfihàn àwọn àmì ẹyẹ rẹ lẹ́yìn to fo gbogbo ẹnu Joseph Parker nínú ìjà to wáyé lọjọ Satide, 31/03 /2018 ...
Read More

Jatijati ni Anthony Joshua na Joseph Parker ni àlè ana

Ninu idije ese kíkan tó wáyé ní ilẹ Biritiko lọjọ Satide to kẹyin oṣù kẹta, 31/03/2018, àná fò lójú ni Anthony Joshua na Joseph Parker
Read More