Smiley face

Asisat Oshoala: Agbaboolu Obirin to pegede julo fodun 2016

Asisat Oshoala, agbaboolu obirin omo ile Naijiria ti gba ami-ẹyẹ agbaboolu obirin ilẹ adulawo to dara ju fun odun 2016 ti ami ẹyẹ CAF Award 2016

Asisat Oshoala tun fi aidunnu rẹ han pelu bi awon ajọ boolu ile adulawo ko se ki n toju sawon agbaboolu obirin gẹgẹ bo ti yẹ.
Koda, ninu alaye rẹ pelu BBC, o ni o ye ki awon obirin rigba ju ohun ti won gba lọwọlọwọ bayii gege bi ere isẹ won.


Ọjọ kesan-an osu kewaa odun 1994 ni won bi Asisat Lamina Oshoala si agbegbe Ikorodu to wa nilu Eko. Ẹgbẹ agbaboolu Arsenal ikọ awon obirin lo si n gba boolu fun loke okun. 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment