Smiley face

Foto: Segun Ogungbe gbesẹ nla fun Odunlade Adekola

Ti a ba n so nipa ise fiimu ilẹ Afirika, ọga ni Segun Ogungbe ninu ise ọpọlọ to fakiki. Agbaọjẹ onise tiata naa ti pada sibudo ere pelu awon ogbontarigi osere bi Odunlade Adekola, Eniola Ajao, Kola Oyewo lati ya fiimu tuntun ti won pe ni AGARTHA. 

Bi a ko tilẹ mọ ohun ti itan naa dale lori bayii, awon asọ ere won fihan gbangba wi pe ise kekere ko ni won dawọle.
Ọba ilu kan...
Eni a gbe iyawo bo wa ba, awon Yoruba ni kii gbe ori igana woran...








Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment