Smiley face

A má tí orí Morocco bonu omi gbígbóná ni to bá di Sunday - Super Eagles

Asekagba idije Chan 2018 eléyìí to ń wáyé ní orileede Morocco ni yóò wá sopin  lọjọ Sande tí ń bo yii.

Asekagba náà yóò sì wáyé láàárín Super Eagles Nigeria àti orileede Morocco.

Nínú ọ̀rọ̀ igbakeji akoni mọọgba ikọ Naijiria, Salisu Yusuf, ó ni kí gbogbo ọmọ Naija lọ mokanla balẹ, nítorí wí pé, tí Sande bá dé, n se ni àwọn yóò ti orí Morocco bonu omi gbígbóná.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment