Smiley face

Orí ènìyàn ni won ka mọ Babalola lọ́wọ́ nipinle Ogun

Àwọn olopaa ìpínlẹ̀ Ogun tí mú ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ ń jẹ Babalola Alex (25yrs) pelu bí wọn ṣe ká orí ènìyàn mọ ọ lọ́wọ́ ni agbegbe Asese. Alex tí jewọ wí pé ọ̀dọ̀ babaláwo tó fẹ́ bá òun ṣe ogún owó ni òun gbé orí náà lọ.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment