Smiley face

Awon foto eto igbeyawo Lionel Messi ati aya re ni Argentina

Gbogbo orileede Argentina lo mi titi nigba ti awon irawo agbaboolu kaakiri agbaye si baalu wole kaakiri origun meererin agbaye nibi ti  Lionel Messi ti gbe n gbe Antonella Roccuzzo niyawo. Die lara awon agbaboolu ti won wa sibe ni Xavi Hernandez, Carles Puyol, Cesc Fabregas ati Sergio Aguero.




 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment