Smiley face

Lola Alao soro nipa awon obirin ti won dalemosu

Lola Alao

Gbajugbaja onserebirin ile Naijiria, Lola Alao ti salaye wi pe, gbogbo obirin ti won ba dale mosu, asise ni won se nigba ti won yan oko. Lola ti oun naa kosi nile oko gba wi pe, asise ni oun se nigba ti oun yan ade ori. 
 


Nibayii, osere naa ti n gbiyanju lati se igbejade fiimu to niise pelu igbe aye awon obirin ti won dalemosu ki awon eniyan le mo idi abajo. 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment