Smiley face

Ọwọ Anthony Joshua, ọmọ ológo, ni àgbà wá báyìí

Ẹ wí fún ẹni tí kò bá mọ kí wọn lọ mọ wí pé, ọwọ́ Anthony Oluwafemi Olaseni Joshua nìkan ni ẹ ti lè rí àmì ẹyẹ agbaye WBA, IBF, WBO ati IBO.

Nígbà tí AJ gbà Joseph Parker mú lọjọ Satide to kọjá yìí , n se bọbọ náà ń jó ShakuShaku lai rí lu.

Àkóbá gafara! 🏃 🏃 🏃 yàgò lọ́nà fún mi Joshua mbo 🏃 🏃

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment