Smiley face

C. Ronaldo kò àwọn ẹbí rẹ wọnú omi

Omo to bá ń sise dééde, ó yẹ kó ni asiko isimi. Kosi sì ohun tó dùn bí kí ènìyàn ló isimi rẹ pẹlu awọn ẹbi rẹ. C Ronaldo lọ ṣe àfihàn òun àti àwọn ẹbí rẹ níbi wọn ti ń ṣeré nínú omi

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment