Smiley face

Cristiano Ronaldo tun ti gba gbogbo irawo agbaboolu to dara ju lo ti Europe patapata

Cristiano Ronaldo
O wu Edumare lo sori ewa fakuko. Sebi won ba Oya ja lasan ni, Sango lo ni seere. won ti gbe ami eye agbaboolu to dara ju todun yii tile Europe fun Cristiano Ronaldo (UEFA Best Player). 

Gbogbo awon ololufee Cristiano Ronaldo ni won ti bere si ni bayo fun aseyori tuntun yii.

Odun 1985 ni won bi C. Ronaldo si Madeirato to wa lorileede Portugal. Gege iwadii awon oniroyin ere idaraya, won ni owo osu ti bobo naa gba n lo bi 6 billion naira o le. Eleyii ko mo awon endorsement lorisiirisii ati ipolowoja ti n se. 




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment