Smiley face

Ifẹ aladun Anuoluwapo pelu Ibironke dun bi oyin

Bi ere bi awada nifẹ Anuoluwapo ati Ibironke bẹrẹ Sugbon Edumare foyin si i, adun si wọ igbe aye awon mejeeji. Lonii ọjọ kerindinlọgbọn osu kẹjọ odun, 26/08/2016, Anuoluwapo Adewunmi gbe Ibironke Okeneye niyawo, awon mejeeji si fi edidi di ife won.


Ọkọ mi, nibo lo wa

Mo si wa ni sọọsi, ẹyin la n re ti now
 Adura wa ni wi pe, ayo, idunnu, ati ibikun yoo ma ba tọkọ-taya naa gbe. Amin. Iru adun bayii ko ni tan nile gbogbo wa. Ase







Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment