Smiley face

Ojise Olorun bi ibeji leyin odun merinlelogun (24) to ti segbeyawo

Leyin igbeyawo odun merinlelogun (24), Oba orun tun pada fi agbara re han pelu bo se fi ibeji ta idile oludasile ijo Jesus The Way and Fire Ministry, Owerri, Rev. Godwin Ogoh ati aya re lore.

Ojise Olorun yii ko le pa ayo naa mora pelu bi omi ekun ayo se n jade loju re nigba to duro niwaju ijo re lati jeri si agbara Olorun.

Ojise Olorun naa fi asiko naa gba awon omo ijo re niyanju lati fi igbagbo won si inu Olorun nigbagbo.

O so fun won wi pe ko si eni ti ipanija ko le deba, sugbon awon to ba fi igbekele won sinu Oluwa ni yoo leke.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment