Smiley face

Orúkọ Abba Kyari tí di ibẹru fún àwọn ọ̀daràn

Akíkanjú ọlọ́pàá ọlọtẹlẹmuyẹ, Abba Kyari, to lè iwájú ikọ elenu márùn-ún lè logoji tí wọn sise láti rí wí pé owó tẹ Evans, ògbólógbòó ajinigbe, lo ti n dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn aláṣẹ ilé ìṣe ọlọ́pàá pelu bi wọn ṣe ṣètò igbega fún gbogbo àwọn ọmọ ikọ rẹ eléyìí tí òun náà kò gbeyin. Abba Kyari ni ọdún márùn-ún lọ gba àwọn láti rí Evans mú nítorí wí pé ọ̀daràn to ni "skill" ni maanu náà. Kyari kan náà ni wọn kesi lórí idigunjale to wáyé nílùú Ọfa. Àìmọye àwọn afurasi ni ọwọ sì ti tẹ báyìí lórí iṣẹlẹ to fi àìmọye èmi ṣòfò.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment