Smiley face

Àkúrẹ́ mi tìtì: Òkìkí Omoyele Sowore ń lọ sókè sí ní joojumọ

Ènìyàn tí kò dá nílé kò lè dá níta. Àìmọye àwọn ènìyàn lọ wà pàdé Omoyele Sowore, ẹni tí ń ṣe ọmọ ipínlẹ̀ Ondo, ni papakọ ofurufu ìlú Àkúré ní kété tí bàálù rẹ bá fún ìpàdé pelu awon olólùfẹ́ rẹ ni ilu náà .

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment