Smiley face

Bukola Saraki tí ṣe tán láti díje fún ipò ààrẹ ọdún 2019

Ààrẹ ilẹ̀ ìgbìmọ̀ asofin àgbà Abuja, Bukola Sàràkí tí fi ìfẹ́ rẹ̀ hàn láti díje ipò aare orileede Nàìjíríà lọ́dún 2019.

Gẹ́gẹ́ bí Olóòtú ìwé Ìròyìn The Boss, Bashorun Dele Momodu ṣe sọ, ó ṣe àlàyé Bukola Sàràkí gẹ́gẹ́ bí akíkanjú olóṣèlú eléyìí to tí mòkun-mọ̀sà nínú oselu Nàìjíríà.

Dele Momodu kò sai mẹ́nu ba àṣeyọrí Sàràkí nígbà tó jẹ́ gómìnà ipínlẹ̀ Kwara àti àwọn akitiyan rẹ gẹ́gẹ́ bí asofin Abuja nígbà tó ń ṣe àkọ́jọpọ̀ ìròyìn rẹ nípa ìfẹ́ Sàràkí láti gbé àpótí ìbò aare ọdún 2019.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment