Smiley face

Àwọn ọlọ́pàá tí gbé Senator Ovie Omo Agege to kò àwọn ọmọ ìta wọlé igbimo asofin

Laarọ yìí ni àwọn ọmọ ìta yawọ ilé igbimo asofin àgbà Abuja tí wọn sì jí ọ̀pá àṣẹ sálọ. Ní báyìí àwọn ọlọ́pàá tí gbé Senator Ovie Omo Agege ẹni ti wọn fura si wí pé  ó ṣe agbeteru àwọn ọmọ ìta náà láti ṣe iṣẹ́ ibi yìí lẹ́yìn tí ilé igbimo rọ̀ọ́ lóye gege bí asofin.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment