Ẹnikẹ́ni tí ìwọ bá nípa láti ṣe iranlowo fún, ohun náà ni enikeji rẹ. Inú ìnira ni ọmọ ọdún méjì àbọ̀ náà wá, kí Edumare bá wà dá sí. Àmìn ...
Read More
Home / Iroyin
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Fayose ṣe tí bẹ àwon ọdẹ lọwẹ sì àwọn Fulani darandaran
Gomina Ipinle Ekiti, Ogbeni Ayodele Pétérù Fayose tí lọ bẹ àwọn ògbójú òde lowe láti dáàbò bo ipinle Ekiti lowo awon Fulani darandaran. Ìgb...
Read More
Ikede: Kèké Maruwa yìí wá fún títa [For Sale]
Gege bí ẹni tó ni se ṣàlàyé, kò sì ohunkóhun tó ṣe kèké náà. Alafia rẹ paye. Ó kàn fẹ́ ta kò lowo rẹ ni. 200k péré ni. E lé pé nomba yìí fú...
Read More
Oko Victoria tí fún ìyá Victoria loyun: Ọ̀rọ̀ Radarada
VICTORIA :Ọkọ mi fún ìyá mi lóyún. Kini kí n ṣe? John: Ìyá ìyàwó mi lọ ń gbé sún mọ́ mi. Ẹ mi náà bá ko bajinatu boo lábẹ́. Mí ó mọ wí pé y...
Read More
Àìmọye àwọn ènìyàn ní won ti ko jáde nile bayii latari iberu àwọn Fulani ni ipinle Benue
Àìmọye àwọn ènìyàn ní won ti ko jáde nile bayii latiri iberu àwọn Fulani darandaran tí wọ́n ṣe ìjàmbá ni ipinle Benue.
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)