Ti omo eni ba dara ka wi, ka maa puro Dayo Amusa leku. Atinu atode, gbogbo re lo pon winnikeke bi moinmoin olororo to kun fun opolopo ...
Read More
Home / Yoruba
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Aye Akamara: Kini Tajudeen Azeez Fe Fi Kidirin Ati Ifun Omo Odun Merin To Pa Se? (E sora, aworan abanilokan je wa nibi)
Tajudeen Azeez omo odun merindinlogun(16) ni owo awon olopa ti te pelu bo se seku pa Ibrahim, omo odun merin (4) kan ni agbegbe Ijanik...
Read More
Morufa Eko 6: Oko Anti Mi Wa Ka Mi Mo Yara Mi Laago Kan Oru Lojo Ti Ko Si Anti Mi Nile
Morufa Eko ti fi leta eleekafa re ranse, eyi si dun mo wa ninu pupo. Fun anfaani eyin ti e ko mo ibi ti a ba de ati eyin ti ko mo ibi ti...
Read More
Odun Ipese Ounje Obo Ni Ilu Thailand
Odun ajobo lodun Ipese Ounje Obo ni ilu Thailand eleyii to ma n waye ni Ipinle Lopburi to wa ni apa ariwa olu ilu Thailand, Bangkok. ...
Read More
"Awon Pasito ati Lemoomu Ma N Yo Wa Ye Ifa Wo Lowo Mi" - Ifayemi Elebuibon
Ojo aboki tipe ni Sabo. Ti a ba n so nipa sowo-sesegun, ogboju babalawo to daju ni Araba Ifayemi Elebuibon. Oun gan-an ni a ba maa...
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)