Ile alajameta miiran tun ti dawo lule ni osan gangan ojo isegun(07/05/13) ni nomba 14, Bashiru Street, off Isheri Road, Ojodu Berger, Lagos. Eniyan meji lo gbe emi mi lojiji nibi isele ibi naa nigba ti awon meji miiran fara pa yannayanna ti won si ti gbe won lo si ile iwosan Lagos State University Teaching Hospital (LASUTH) fun itoju to peye. ki Edua oke ba wa dawo ibi duro. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)

0 comments:
Post a Comment