Mandela dubule aisan lonii, joojumo ni awon eniyan n gbe ohun adura soke fun un ni ilu South Africa wi pe ki Olorun fi kun ojo aye re laye. Mandela, eni ti yoo pe omo odun marunlelaadorun(95years old) ninu osu keje, ojo kejidinlogun odun 2013, lo wu gbogbo araye bi ki olojo maa ti de ba baba yii lori aisan latari ohun ribiribi ti o ti gbe se ninu iran awon eniyan dudu.
![]() |
| Feb 11,1990. Iwode ajoyo lojo ti won kede idasile Mandela lewon leyin odun metadinlogbon to ti wa ni ahamo |
![]() |
| Feb 13, 1990. Papa isere City Succer ti Soweto nibi ti awon omilegbe eniyan ti wa pade Mandela fun ajoyo idasilere loko awon amunisin |
![]() |
| 1994, nigba ti gbogbo ilu so wi pe Mandela la won fe ko maa se olori ile awon |
July 18,1990, nigba ti Mandela pe omo odun mejilelaadorin(72). O tun je ojo ibi akoko ti yoo se leyin ti o jade lewon
Iwadii fi ye wa wi pe Mandela lo odun mejidinlogun(18) ninu aworan yara ewon oke yii ninu odun metadinlogbon(27) to lo ni gbaga





0 comments:
Post a Comment