Smiley face

Baba Gbe Ijoba Sile Fun Omo Re

Sheikh Hamad bin Khalifa Al Thani, eni ti o ti n se olori ile Qatar lati nnkan bi odun mejidinlogun bayii ti kede lati gbe ijoba re sile fun omo re, Sheikh Tamim bin Hamad Al Thani, eni odun metalelogun(33).


Olayemi Olatilewa
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment