Lopin ose to koja yii, Wizkid pate orin ni ilu Abuja. Sugbon iyalenu lo je wi pe aimoye aga lo sofo ninu gbogan ti Ayo Balogun ti pate alujo pelu bi ipolowo Wizkid-mbo' se rinle saaju ojo isinmi to koja yii.
Ayo fun ra re ti soro lori isele naa. Oni ijoko gbogboogbo si gbagede ariya naa ni egberun merin (4k), nigba ti ijoko olola je egberun mewa(10k), ijoko eleeyan merin pelu tabili si n lo bi nnkan bi egberun lona oodunrun owo naira(300k).
O ni pupo ibi ti aga ti sofo lo je ijoko awon olola eleyii ti owo re po die.
Ju gbogbo re lo, Wizkid so wi pe isele naa ko da oun lokan ru rara.

Kin lo le fa tofi ri be? O ga o! Morope o ye ki omode kunrin na o yerarewo finnifinni. Toripe, bi o ba nidi aja tomoni ri kan o ni dede ma gbo losan gangan.
ReplyDelete@Austine,Oro naa seni ni kayeefi oo
ReplyDelete