Smiley face

Leyin Odun Mejila Ti Sunny Neji Ti Se Igbeyawo

Oni lo pe odun mejila ti agba olorin Highlife, Sunny Neji ti se igbeyawo. Igbeyawo naa ko baje, Edua oke tun fi omo rere eleyii ti n se adun igbeyawo da won lola.

Olayemi, mo ki won. Mo se adura wi pe adun ko ni tan ni ile toko-taya naa. Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment