Smiley face

[Foto] "Faaji N San Lagbo Ayefele Pelu Awon Gbajumo" Otunba Kola Olootu

Otunba Kola Olootu (Gomina Fiban ti Ipinle Oyo) naa gbeyo sagbo Ayefele losan oni yii nibi ifilole orin tuntun Yinka Ayefele 'Comforter' pelu awon omo egbe Fiban ti Ipinle Oyo bi Yemi Shonde, Saheed Mr Sport, Ologbojo ati bee bee lo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment